Ka àwọn ayokà isàlè yil, ki o si dáhún àwọn ibéèrè tí ó tèlé won. Nínú abúlé aláàánú kan tí ó wà láàárín àwọn òkè aláwo ewé, ìșẹ̀lẹ̀ abàmì kan sẹlẹ̀ tí ó yà...

Assessment: JAMB UTME - Yoruba Language - 2025 Subject: Yoruba Language

Question 1 Report

Ka àwọn ayokà isàlè yil, ki o si dáhún àwọn ibéèrè tí ó tèlé won.
Nínú abúlé aláàánú kan tí ó wà láàárín àwọn òkè aláwo ewé, ìșẹ̀lẹ̀ abàmì kan sẹlẹ̀ tí ó yà àwọn àgbàlagbà abúlé lẹ́nu. Ní gbogbo òwúrọ̀, àwọn ará
abúlé máa ń jí láti rí pé ọgbà wọn ti bàjẹ́, oúnjẹ wọn sì dínkù láìníye. Ní ìbrẹ̀, wọ́n fi ẹ̀sùn kàn àwọn ẹranko igbó. Șùgbọ́n ọdẹ abúlé sọ pé kò sí ipa ẹsẹ̀
kankan tí wọ́n rí láti fihàn pé ẹranko ni . Olórí abúlé pè gbogbo ènìyàn jọ, ó sì dá ẹgbẹ figilanté tó máa ń ṣọ́ alẹ́ sílẹ̀.
Àwọn tó yá ara wọn sílẹ̀ fún isé yí mú atupa àti ọpá, wọ́n jókòó nínú òkùnkùn. ọ̀pọ̀ alẹ́ ni kò sí ìșẹ̀lẹ̀ kankan. Șùgbọ́n ní alẹ́ karùn-ún, nígbà tí òșùpá ń
tan lójú ọ̀run, won gbo kìkún legbeé abà ẹ̀lùbọ̀ olórí abúlé. Wọn sare lọ, wón sì rí àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin kan láti abúlé kejì, tí wọ́n ń sa lọ
Ní ọjọ kejì, àwọn àgbàlagbà abúlé lọ sí abúlé yẹn láti bá wọn sọrọ. Ó hàn kedere pé àwọn ọmọ yìí jẹ aláìní, tí ìkànlù omi burúkú kan ti run gbogbo
pẹ̀lú oúnjẹ tí wọ́n jí.
ọgbà wọn. Kódà, ó jẹ́ pé wọ́n ń jì oúnjẹ kí wọ́n lè yè. Eleyi jẹ̀ ohun ti o bani lọkan jẹ̀, wọn si pinnu láti fi oúnjẹ tí wọ́n ní kù fún wọn dipo ìjíyà. Láti ọjọ́
yẹn lọ, ìbáșepọ̀ àti àjọșe dájú láàárín àwọn abúlé méjèèjì.

Kí ni abajade tó yọ láti inú iṣẹlẹ̀ yìí?

Answer Details

This question asks for the overall consequence of everything described in the passage, which means looking at how the story ends rather than at any single incident within it.

The narrative moves from suspicion and a night watch, to the discovery that hungry children from a nearby village had been taking food because a flood had ruined their own farmland, to the elders responding with generosity instead of punishment. The passage's final sentence states directly that from that day onward, a cordial relationship and cooperation developed between the two villages.

That closing statement is the outcome the question is asking about. The events did not lead to lasting sadness, further food damage, or continued theft; they led to reconciliation and a stronger bond between the communities, which is the resolution the whole story builds toward.

When a comprehension question asks for a story's outcome, always check the final lines of the passage, since narratives are usually structured to resolve their central conflict there.

Download The App On Google Playstore

Everything you need to excel in your exams

Green Bridge CBT Mobile App
Personalized AI Learning Chat Assistant
200,000+ Exam Questions Across IGCSE, JAMB, WAEC & NECO
Over 3,900 Lesson Notes
Offline Support - Learn Anytime, Anywhere
Green Bridge Timetable
Literature Summaries & Potential Questions
Track Your Performance & Progress
In-depth Explanations for Comprehensive Learning