Question 1 Report
Ka àwọn ayokà isàlè yil, ki o si dáhún àwọn ibéèrè tí ó tèlé won.
Nínú abúlé aláàánú kan tí ó wà láàárín àwọn òkè aláwo ewé, ìṣẹ̀lẹ̀ abàmì kan șẹlẹ̀ tí ó yà àwọn àgbàlagbà abúlé lénu. Ní gbogbo òwúrọ̀, àwọn ará
abúlé máa ń jí láti rí pé ọgbà wọn ti bàjẹ́, oúnjẹ wọn sì dínkù láìníye. Ní ìbẹ̀rẹ̀, wọ́n fi sùn kàn àwọn ẹranko igbó. Șùgbọ́n ọdẹ abúlé sọ pé kò sí ipa ẹsẹ̀
kankan tí wọ́n rí láti fihàn pé ẹranko ni . Olórí abúlé pè gbogbo ènìyàn jọ, ó sì dá ẹgbẹ figilanté tó máa ń ṣọ́ alẹ́ sílẹ̀.
Àwọn tó yá ara wọn sílẹ̀ fún isé yí mú atupa àti ọpá, wọ́n jókòó nínú òkùnkùn. ọ̀pọ̀ alẹ́ ni kò sí ìșẹ̀lẹ̀ kankan. Șùgbọ́n ní alẹ́ karùn-ún, nígbà tí òșùpá ń
tan lójú ọ̀run, won gb kìkún legbeé abà ẹ̀lùbọ̀ olórí abúlé. Wọn sare lọ, wọ́n sì rí àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin kan láti abúlé kejì, tí wọ́n ń sa lọ
Ní ọjọ kejì, àwọn àgbàlagbà abúlé lọ sí abúlé yẹn láti bá wọn sọrọ. Ó hàn kedere pé àwọn ọmọ yìí jẹ aláìní, tí ìkànlù omi burúkú kan ti run gbogbo
pẹ̀lú oúnję tí wọ́n jí.
ọgbà wọn. Kódà, ó jẹ́ pé wọ́n ń jì oúnjẹ kí wọ́n lè yè. Eleyi jẹ̀ ohun ti o bani lọkan jẹ̀, wọn si pinnu láti fi oúnjẹ tí wọ́n ní kù fún wọn dipo ìjíyà. Láti ọjọ́
yẹn lọ, ìbáșepọ̀ àti àjọṣe dájú láàárín àwọn abúlé méjèèjì.
Kí ni ișòro tí àwọn ará abúlé kókọ́ dojukọ?
The passage opens by describing what the villagers discovered every morning: their farmland kept getting damaged and their food supply kept reducing without any clear cause. This was the very first problem the village faced, before any suspects, hunters, or vigilante groups are mentioned.
Wild animals entering the village is only the villagers' first guess about the cause of the problem, not the problem itself, and the passage goes on to say the hunter found no footprints to support that idea. An epidemic disease and a shortage of water are not mentioned anywhere in the passage; neither illness nor lack of water is described as affecting the villagers.
Because the passage explicitly states that the villagers woke to find their farmland ruined and their food reduced without measure, the initial problem they faced was the destruction of their farmland together with the ongoing disappearance of their food.
Examination tip: in a comprehension passage, distinguish the actual event described from characters' guesses about its cause, since a question asking what problem occurred wants the event itself, not the suspected cause.
Everything you need to excel in your exams