Ka àwọn ayokà isàlè yil, ki o si dáhún àwọn ibéèrè tí ó tèlé won. Nínú abúlé aláàánú kan tí ó wà láàárín àwọn òkè aláwo ewé, ìșẹ̀lẹ̀ abàmì kan șẹlẹ̀ tí ó yà...

Assessment: JAMB UTME - Yoruba Language - 2025 Subject: Yoruba Language

Question 1 Report

Ka àwọn ayokà isàlè yil, ki o si dáhún àwọn ibéèrè tí ó tèlé won.
Nínú abúlé aláàánú kan tí ó wà láàárín àwọn òkè aláwo ewé, ìșẹ̀lẹ̀ abàmì kan șẹlẹ̀ tí ó yà àwọn àgbàlagbà abúlé lénu. Ní gbogbo òwúrọ̀, àwọn ará
abúlé máa ń jí láti rí pé ọgbà wọn ti bàjẹ́, oúnjẹ wọn sì dínkù láìníye. Ní ìbẹ̀rẹ̀, wọ́n fi sùn kàn àwọn ẹranko igbó. Șùgbọ́n ọdẹ abúlé sọ pé kò sí ipa ẹsẹ̀
kankan tí wọ́n rí láti fihàn pé ẹranko ni . Olórí abúlé pè gbogbo ènìyàn jọ, ó sì dá ẹgbẹ figilanté tó máa ń ṣọ́ alẹ́ sílẹ̀.
Àwọn tó yá ara wọn sílẹ̀ fún isé yí mú atupa àti ọpá, wọ́n jókòó nínú òkùnkùn. Òpọ̀ alẹ́ ni kò sí ìșẹ̀lẹ̀ kankan. Șùgbọ́n ní alẹ́ karùn-ún, nígbà tí òșùpá ń
tan lójú ọ̀run, won gbo kìkún légbèé abà èlùbọ̀ olórí abúlé. Wọn sare lọ, wọ́n sì rí àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin kan láti abúlé kejì, tí wọ́n ń sa lọ
Ní ọjọ kejì, àwọn àgbàlagbà abúlé lọ sí abúlé yẹn láti bá wọn sọrọ. Ó hàn kedere pé àwọn ọmọ yìí jẹ aláìní, tí ìkànlù omi burúkú kan ti run gbogbo
pẹ̀lú oúnjẹ tí wọ́n jí.
ọgbà wọn. Kódà, ó jẹ́ pé wọ́n ń jì oúnjẹ kí wọ́n lè yè. Eleyi jẹ̀ ohun ti o bani lọkan jẹ̀, wọn si pinnu láti fi oúnjẹ tí wọ́n ní kù fún wọn dipo ìjíyà. Láti ọjọ́
yẹn lọ, ìbáșepọ̀ àti àjọṣe dájú láàárín àwọn abúlé méjèèjì.

Kí ni àwọn àgbàlagbà șe lẹ́yìn tí wọ́n mọ ohun tó ṣẹlẹ̀ gangan?

Answer Details

This question checks whether the reader has followed the passage to its resolution, where the villagers' response changes once they learn the full circumstances behind the earlier disturbance.

After the elders travel to the neighbouring village and speak with the people there, they discover that the young people who had been taking food were driven to it by hardship: a flood had destroyed their farmland, leaving their families without enough to eat. Faced with this information, the passage states plainly that the elders chose to give out of their own remaining food to help them, rather than punish them for what had happened.

This response is what allows the story to end with friendly relations between the two villages. Choosing kindness over blame or punishment is the turning point of the narrative, and it explains why the passage closes by describing lasting cooperation between the communities rather than continued suspicion.

In comprehension passages built around conflict and resolution, the ending usually reveals the story's central value; here that value is compassion shown once the true cause of a problem is understood.

Download The App On Google Playstore

Everything you need to excel in your exams

Green Bridge CBT Mobile App
Personalized AI Learning Chat Assistant
200,000+ Exam Questions Across IGCSE, JAMB, WAEC & NECO
Over 3,900 Lesson Notes
Offline Support - Learn Anytime, Anywhere
Green Bridge Timetable
Literature Summaries & Potential Questions
Track Your Performance & Progress
In-depth Explanations for Comprehensive Learning