Question 1 Report
Ka àwọn ayokà isàlè yil, ki o si dáhún àwọn ibéèrè tí ó tèlé won.
Nínú abúlé aláàánú kan tí ó wà láàárín àwọn òkè aláwo ewé, ìșẹ̀lẹ̀ abàmì kan sẹlẹ̀ tí ó yà àwọn àgbàlagbà abúlé lẹ́nu. Ní gbogbo òwúrọ̀, àwọn ará
abúlé máa ń jí láti rí pé ọgbà wọn ti bàjẹ́, oúnjẹ wọn sì dínkù láìníye. Ní ìbẹ̀rẹ̀, wọ́n fi ẹ̀sùn kàn àwọn ẹranko igbó. Sùgbọ́n ọdẹ abúlé sọ pé kò sí ipa ẹsẹ̀
kankan tí wọ́n rí láti fihàn pé ẹranko ni . Olórí abúlé pè gbogbo ènìyàn jọ, ó sì dá ẹgbẹ figilanté tó máa ń sọ́ alẹ́ sílẹ̀.
Àwọn tó yá ara wọn sílẹ̀ fún isé yí mú atupa àti ọpá, wọ́n jókòó nínú òkùnkùn. ọ̀pọ̀ alẹ́ ni kò sí ìșẹ̀lẹ̀ kankan. Șùgbọ́n ní alẹ́ karùn-ún, nígbà tí òșùpá ń
tan lójú ọ̀run, won gbo kìkún légbèé abà ẹ̀lùbọ̀ olórí abúlé. Wọn sare lọ, wọ́n sì rí àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin kan láti abúlé kejì, tí wọ́n ń sa lọ
Ní ọjọ kejì, àwọn àgbàlagbà abúlé lọ sí abúlé yẹn láti bá wọn sọrọ. Ó hàn kedere pé àwọn ọmọ yìí jẹ aláìní, tí ìkànlù omi burúkú kan ti run gbogbo
pẹ̀lú oúnjẹ tí wọ́n jí.
ọgbà wọn. Kódà, ó jẹ́ pé wọ́n ń jì oúnjẹ kí wọ́n lè yè. Eleyi jẹ̀ ohun ti o bani lọkan jẹ̀, wọn si pinnu láti fi oúnjẹ tí wọ́n ní kù fún wọn dipo ìjíyà. Láti ọjọ́
yẹn lọ, ìbáșepọ̀ àti àjọșe dájú láàárín àwọn abúlé méjèèjì.
Kí ló jẹ́ kí wọ́n mọ̀ pé kì í șe ẹranko ni?
The passage explains that although the villagers first suspected wild animals, the village hunter, who is skilled at tracking animals, examined the scene and reported that he could find no animal footprints at all to support the idea that an animal was responsible.
No garden being eaten is not what the passage says; the garden was in fact being damaged, which is precisely the problem being investigated. The passage never mentions that an animal was actually caught, so that cannot be the reason the villagers changed their thinking. Absence of animal noise is also not stated anywhere in the passage as evidence.
Because it was specifically the hunter's report of finding no animal footprints that undermined the idea of an animal being responsible, that report is what made the villagers realise it was not an animal.
Examination tip: when a comprehension question asks what made a character realise something, search the passage for the specific piece of evidence given, here the hunter's statement about footprints, rather than assuming a general explanation.
Everything you need to excel in your exams