Ka àwọn ayokà isàlè yil, ki o si dáhún àwọn ibéèrè tí ó tèlé won. Nínú abúlé aláàánú kan tí ó wà láàárín àwọn òkè aláwo ewé, ìșẹ̀lẹ̀ abàmì kan sẹlẹ̀ tí ó yà...

Assessment: JAMB UTME - Yoruba Language - 2025 Subject: Yoruba Language

Question 1 Report

Ka àwọn ayokà isàlè yil, ki o si dáhún àwọn ibéèrè tí ó tèlé won.
Nínú abúlé aláàánú kan tí ó wà láàárín àwọn òkè aláwo ewé, ìșẹ̀lẹ̀ abàmì kan sẹlẹ̀ tí ó yà àwọn àgbàlagbà abúlé lẹ́nu. Ní gbogbo òwúrọ̀, àwọn ará
abúlé máa ń jí láti rí pé ọgbà wọn ti bàjẹ́, oúnjẹ wọn sì dínkù láìníye. Ní ìbẹ̀rẹ̀, wọ́n fi ẹ̀sùn kàn àwọn ẹranko igbó. Șùgbọ́n ọdẹ abúlé sọ pé kò sí ipa ẹsẹ̀
kankan tí wón rí láti fihàn pé ẹranko ni . Olórí abúlé pè gbogbo ènìyàn jọ, ó sì dá ẹgbẹ figilanté tó máa ń ṣọ́ alẹ́ sílẹ̀.
Àwọn tó yá ara wọn sílẹ̀ fún isé yí mú atupa àti ọpá, wọ́n jókòó nínú òkùnkùn. ọ̀pọ̀ alẹ́ ni kò sí ìșẹ̀lẹ̀ kankan. Șùgbọ́n ní alẹ́ karùn-ún, nígbà tí òșùpá ń

Ní ọjọ kejì, àwọn àgbàlagbà abúlé lọ sí abúlé yẹn láti bá wọn sọrọ. Ó hàn kedere pé àwọn ọmọ yìí jẹ aláìní, tí ìkànlù omi burúkú kan ti run gbogbo
pẹ̀lú oúnjẹ tí wọ́n jí.
tan lójú ọ̀run, won gbo kìkún legbeé abà ẹ̀lùbọ̀ olórí abúlé. Wọn sare lọ, wọ́n sì rí àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin kan láti abúlé kejì, tí wọ́n ń sa lọ

ọgbà wọn. Kódà, ó jẹ́ pé wọ́n ń jì oúnjẹ kí wọ́n lè yè. Eleyi jẹ̀ ohun ti o bani lọkan jẹ̀, wọn si pinnu láti fi oúnjẹ tí wọ́n ní kù fún wọn dipo ìjíyà. Láti ọjọ́
yẹn lọ, ìbáșepọ̀ àti àjọṣe dájú láàárín àwọn abúlé méjèèjì.

Kí ni àwọn olùșọ́ rí ní alẹ́ yẹn?

Answer Details

When the night watchers ran towards the sound near the yam barn, the passage says they found some boys and girls from the neighbouring village who were fleeing with food they had stolen.

The passage does not describe the hunter behaving strangely on that night, nor does it mention the lantern catching fire. It also makes clear, through the earlier report of no animal footprints and this later discovery, that the culprits were not animals eating the garden but children taking food.

Because the passage explicitly states that the watchers found boys and girls running away with stolen food, that is what they saw that night.

Examination tip: comprehension questions about the climax of a story want the concrete detail the passage gives, here the identity of the culprits caught in the act, not an inferred or general description.

Download The App On Google Playstore

Everything you need to excel in your exams

Green Bridge CBT Mobile App
Personalized AI Learning Chat Assistant
200,000+ Exam Questions Across IGCSE, JAMB, WAEC & NECO
Over 3,900 Lesson Notes
Offline Support - Learn Anytime, Anywhere
Green Bridge Timetable
Literature Summaries & Potential Questions
Track Your Performance & Progress
In-depth Explanations for Comprehensive Learning