Ka àwọn ayokà isàlè yil, ki o si dáhún àwọn ibéèrè tí ó tèlé won. Òpọ̀ ọdún sẹ́yìn, àșà Yorùbá jẹ́ àfihàn ìdánimọ̀, ìbùkún àti ìpẹ̀yà fún àwọn tí wọ́n bá tẹ...

Assessment: JAMB UTME - Yoruba Language - 2025 Subject: Yoruba Language

Question 1 Report

Ka àwọn ayokà isàlè yil, ki o si dáhún àwọn ibéèrè tí ó tèlé won.
Òpọ̀ ọdún sẹ́yìn, àșà Yorùbá jẹ́ àfihàn ìdánimọ̀, ìbùkún àti ìpẹ̀yà fún àwọn tí wọ́n bá tẹ̀síwájú nínú rẹ̀. Àșà àti ìṣe Yorùbá dá lórí ìbáșepọ̀ rere, ìbùkún
àwọn àgbà, ìtẹ́lọ́run ìdílé, àti ìmọ̀ràn tí ó dá lórí ọgbọ́n àwọn baba-nlá wa. Ní gbogbo agbondan Yorùbá, ìyàwó tí a fẹ́ sílẹ, orúkọ tí a fún ọmọ, àwọn
àșà bí a șe ń sajọyọ̀, tàbí bó ṣe yẹ kí a șe ìrántí ẹni tó kú, gbogbo wọ́n ní ìtumọ̀ púpọ̀.
Șùgbón, ní àgbáyé òde-òní, pẹ̀lú ìtẹ̀síwájú ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ àti imọ̀-ẹrọ, ọ̀pọ̀ àwọn ọmọde àti àwọn ọdọ ti kọ̀ kọ́ àti àșà àwọn baba wọn sílẹ̀. Wón ń fi ẹ̀sùn
kàn an pé àșà jẹ́ ohun ateyinwa, kó sì ní ọ̀rọ̀ tó wúlò mọ́. Kíákíá ni wọ́n fi ń gbàgbọ́ pé àwọn àșà tó jẹ́ ti àwọn orílẹ̀-èdè yòókù dàgbà ju tiwọn lọ.
Ọpọ̀ àwọn obi àti olùkọ́ ló ti wá fìdí re mulẹ̀ bayi pé àìmọ̀ àșà lórí àwọn ọmọde ń fa ìjìyà àti ìtànkálẹ̀ ìbànújẹ nínú awujọ. Bí àpẹẹrẹ, ọmọ tí kò mọ̀
ìtéríba, kò ní lè mọyì àgbà, kó sì ní ifọkàn tán láti fi ọgbọ́n gbà ìpinnu. Nípa bẹ́ẹ̀, àṣà Yorùbá kò yẹ kí ó kú tàbí di aimo, ó yẹ kí a fi ran àwọn ọmọ wa
lọ́wọ́ nínú ẹ̀kọ́, isé, àti ìgbésí-ayé won.

Kí ni àpilẹ̀kọ sọ pé àșà Yorùbá jẹ́?

Answer Details

The passage opens by defining Yoruba culture directly: "àṣà Yorùbá jẹ́ àfihàn ìdánimọ̀, ìbùkún àti ìpẹ̀yà fún àwọn tí wọ́n bá tẹ̀síwájú nínú rẹ̀" (Yoruba culture is a display of identity, blessing, and heritage for those who continue in it). The passage's own words state that culture is a manifestation of identity.

Good character (ọmọlúwàbí), modern technology, and the religious history of the Egyptians are not statements the passage makes about what culture is; they either appear elsewhere in a different sense or do not appear in the passage's definition at all.

When a comprehension question asks what a passage says something is, return to the exact sentence in the text that defines it rather than relying on general knowledge of the topic.

Download The App On Google Playstore

Everything you need to excel in your exams

Green Bridge CBT Mobile App
Personalized AI Learning Chat Assistant
200,000+ Exam Questions Across IGCSE, JAMB, WAEC & NECO
Over 3,900 Lesson Notes
Offline Support - Learn Anytime, Anywhere
Green Bridge Timetable
Literature Summaries & Potential Questions
Track Your Performance & Progress
In-depth Explanations for Comprehensive Learning