Question 1 Report
Ka àwọn ayokà isàlè yil, ki o si dáhún àwọn ibéèrè tí ó tèlé won.
Òpọ̀ ọdún sẹ́yìn, àșà Yorùbá jẹ́ àfihàn ìdánimọ̀, ìbùkún àti ìpẹ̀yà fún àwọn tí wọ́n bá tẹ̀síwájú nínú rẹ̀. Àà àti ìse Yorùbá dá lórí ìbáșepọ̀ rere, ìbùkún
àwọn àgbà, ìtẹ́lọ́run ìdílé, àti ìmọ̀ràn tí ó dá lórí ọgbọ́n àwọn baba-nlá wa. Ní gbogbo agbondan Yorùbá, ìyàwó tí a fẹ́ sílẹ, orúkọ tí a fún ọmọ, àwọn
àșà bí a șe ń sajọyọ̀, tàbí bó ṣe yẹ kí a șe ìrántí ẹni tó kú, gbogbo wọ́n ní ìtumọ̀ púpọ̀.
Șùgbọ́n, ní àgbáyé òde-òní, pẹ̀lú ìtẹ̀síwájú ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ àti imọ̀-ẹrọ, ọ̀pọ̀ àwọn ọmọde àti àwọn ọdọ ti kọ̀ ẹ̀kọ́ àti àṣà àwọn baba wọn sílẹ̀. Wón ń fi ẹ̀sùn
kàn an pé àșà jẹ́ ohun ateyinwa, kó sì ní ọ̀rọ̀ tó wúlò mọ́. Kíákíá ni wọ́n fi ń gbàgbọ́ pé àwọn àșà tó jẹ́ ti àwọn orílẹ̀-èdè yòókù dàgbà ju tiwọn lọ.
Ọpọ̀ àwọn obi àti olùkọ́ ló ti wá fìdí re mulẹ̀ bayi pé àìmọ̀ àșà lórí àwọn ọmọde ń fa ìjìyà àti ìtànkálẹ̀ ìbànújẹ nínú awujọ. Bí àpẹẹrẹ, ọmọ tí kò mọ̀
ìtẹ́ríba, kò ní lè mọyì àgbà, kó sì ní ifọkàn tán láti fi ọgbọ́n gbà ìpinnu. Nípa bẹ́ẹ̀, àṣà Yorùbá kò yẹ kí ó kú tàbí di aimo, ó yẹ kí a fi ran àwọn ọmọ wa
lọ́wọ́ nínú ẹ̀kọ́, isé, àti ìgbésí-ayé won.
Kí ni ọmọ tí kò mọ̀ àșà kì í mọ̀?
The passage describes what a culturally untrained child lacks: "ọmọ tí kò mọ̀ ìtẹ́ríba, kò ní lè mọyì àgbà, kó sì ní ìfọkàn tán láti fi ọgbọ́n gbà ìpinnu" (a child who does not know respect cannot value elders, and will not have the confidence to make wise decisions). The passage explicitly names respect and the wisdom to make sound decisions as what such a child is missing.
The passage does not connect this lack to the ability to lie, to food choices, or to relationships in general; those ideas are not part of the sentence describing what the child fails to know.
When a question asks what a passage says someone lacks, match your answer to the exact qualities the text lists, here respect and sound judgement in decision-making.
Everything you need to excel in your exams