Ka àwọn ayokà isàlè yil, ki o si dáhún àwọn ibéèrè tí ó tèlé won. Òpọ̀ ọdún sẹ́yìn, àșà Yorùbá jẹ́ àfihàn ìdánimọ̀, ìbùkún àti ìpẹ̀yà fún àwọn tí wọ́n bá tẹ...

Assessment: JAMB UTME - Yoruba Language - 2025 Subject: Yoruba Language

Question 1 Report

Ka àwọn ayokà isàlè yil, ki o si dáhún àwọn ibéèrè tí ó tèlé won.
Òpọ̀ ọdún sẹ́yìn, àșà Yorùbá jẹ́ àfihàn ìdánimọ̀, ìbùkún àti ìpẹ̀yà fún àwọn tí wọ́n bá tẹ̀síwájú nínú rẹ̀. Àșà àti ìṣe Yorùbá dá lórí ìbáṣepọ̀ rere, ìbùkún
àwọn àgbà, ìtẹ́lọ́run ìdílé, àti ìmọ̀ràn tí ó dá lórí ọgbọ́n àwọn baba-nlá wa. Ní gbogbo agbondan Yorùbá, ìyàwó tí a fẹ́ sílẹ, orúkọ tí a fún ọmọ, àwọn
àșà bí a șe ń sajọyọ̀, tàbí bó ṣe yẹ kí a șe ìrántí ẹni tó kú, gbogbo wọ́n ní ìtumọ̀ púpọ̀.
Șùgbọ́n, ní àgbáyé òde-òní, pẹ̀lú ìtẹ̀síwájú ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ àti imọ̀-ẹrọ, ọ̀pọ̀ àwọn ọmọde àti àwọn ọdọ ti kọ̀ ẹ̀kọ́ àti àșà àwọn baba wọn sílẹ̀. Wọ́n ń fi ẹ̀sùn
kàn an pé àșà jẹ́ ohun ateyinwa, kó sì ní ọ̀rọ̀ tó wúlò mọ́. Kíákíá ni wọ́n fi ń gbàgbọ́ pé àwọn àșà tó jẹ́ ti àwọn orílẹ̀-èdè yòókù dàgbà ju tiwọn lọ.
Ọpọ̀ àwọn obi àti olùkọ́ ló ti wá fìdí re mulẹ̀ bayi pé àìmọ̀ àșà lórí àwọn ọmọde ń fa ìjìyà àti ìtànkálẹ̀ ìbànújẹ nínú awujọ. Bí àpẹẹrẹ, ọmọ tí kò mọ̀
ìtéríba, kò ní lè mọyì àgbà, kó sì ní ifọkàn tán láti fi ọgbọ́n gbà ìpinnu. Nípa bẹ́ẹ̀, àșà Yorùbá kò yẹ kí ó kú tàbí di aimo, ó yẹ kí a fi ran àwọn ọmọ wa
lọ́wọ́ nínú ẹ̀kọ́, isé, àti ìgbésí-ayé won.

Èka wo ni àșà Yorùbá kó jọ?

Answer Details

The passage lists the foundations of Yoruba culture and practice in one sentence: good relationships (íbáṣepọ̀ rere), the blessing of elders, family contentment (ìtẹ́lọrun ídílé), and advice built on the wisdom of the ancestors (ọgbọ́n àwọn baba-nlá wa). The question asks which areas or branches Yoruba culture brings together, so the correct option must match this list.

The option naming relationship, contentment, and the application of wisdom (íbáṣepọ̀, ìtẹ́lọrun, ímúlò ọgbọ́n) directly mirrors these three pillars named in the passage, making it the correct answer.

The other options introduce items the passage never groups together under culture, such as song, fighting, and medicine, or religion, evil, and prayer. These sound like they could belong to a general discussion of Yoruba life, but none of them appear in the specific sentence the question is testing, so they must be rejected.

Download The App On Google Playstore

Everything you need to excel in your exams

Green Bridge CBT Mobile App
Personalized AI Learning Chat Assistant
200,000+ Exam Questions Across IGCSE, JAMB, WAEC & NECO
Over 3,900 Lesson Notes
Offline Support - Learn Anytime, Anywhere
Green Bridge Timetable
Literature Summaries & Potential Questions
Track Your Performance & Progress
In-depth Explanations for Comprehensive Learning