Question 1 Report
LÍTÍRÉßÕ Ìwé Àkójôpõ Ewi Alohùn Yorùbá ni ìbéèrè dá lé. Nínú Èfê, kí ni àÿírí ìyàwó õgá Súlè tí õkôrin tú?
Answer Details
Inú ôjà ni àÿírí rê ti tú pé olè ni.