Question 1 Report
ÌßÊßE Èwo ni ó fi ìgbàgbö Yorùbá nípa ayé lëyìn ikú hàn nínú ìwònyí?
Answer Details
Yorùbá gbàgbö pé àwôn êdá tí wön ti kú tí wön tõrun wá sí ayé ni egúngún.