Question 1 Report
ÈDÈ
Àpççrç õrõ àyálò níbi tí köþsónáýtì ti parí õrõ ni
Answer Details
Láti inú èdè Gêësì “thug” ni a ti yá õrõ yìí lò; ìlànà òfin õrõ Yorùbá ló jë ká fí fáwëlì i parí rê nígbà tí a pèé.