Question 1 Report
LÍTÍRÉßÕ Ìwé Ojú Òÿùpá, apá kìíní ni ìbéèrè dá lé. Nínú ìtàn Oríkõ, kí ni Õrúnmìlà fi obì aláwë-mëta tí ó gbà löwö Jégéjégé ÿe?
Answer Details
Ó fi bèèrè ibo löwö Ifá ni.