Question 1 Report
Answer Details
Lëyìn ìfójúsóde, tí õdõkùnrin bá ti rí obìnrin tó wù ú láti fë, ojúÿe àwôn òbí ló kù làti ÿe ìwádìí nípa irú ilé tí ômôbìnrin náà ti wá.