Question 1 Report
ÈDÈ
Õrõ wo ni kò ní apààlà sílébù nínú Olú á ra bàtà?
Answer Details
“Á” nìkan ni kò ÿe é gé sí sílébú nínú gbogbo õrõ inú gbólóhùn náà.