Question 1 Report
LÍTÍRÉßÕ Ìwé Ojú Òÿùpá, apá kìíní ni ìbéèrè dá lé. Nínú ìtàn Ìjà Ìlêkê, kí ni Kékeré awo ní kí ôba fi bô òrìÿà odù?
Answer Details
Ìgbin kan ÿoÿo.